-
Jóòbù 36:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ó dájú pé àwọn ọ̀rọ̀ mi kì í ṣe irọ́;
Ẹni tí ìmọ̀ rẹ̀ pé+ nìyí níwájú rẹ.
-
-
Róòmù 11:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ọrọ̀ àti ọgbọ́n àti ìmọ̀ Ọlọ́run mà jinlẹ̀ o! Ẹ wo bí àwọn ìdájọ́ rẹ̀ ṣe jẹ́ àwámáridìí tó, tí àwọn ọ̀nà rẹ̀ sì kọjá àwárí!
-