ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 36:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ó dájú pé àwọn ọ̀rọ̀ mi kì í ṣe irọ́;

      Ẹni tí ìmọ̀ rẹ̀ pé+ nìyí níwájú rẹ.

  • Sáàmù 18:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Pípé ni ọ̀nà Ọlọ́run tòótọ́;+

      Ọ̀rọ̀ Jèhófà jẹ́ èyí tí a yọ́ mọ́.+

      Apata ló jẹ́ fún gbogbo àwọn tó fi í ṣe ibi ààbò.+

  • Sáàmù 104:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Àwọn iṣẹ́ rẹ mà pọ̀ o, Jèhófà!+

      Gbogbo wọn lo fi ọgbọ́n ṣe.+

      Ayé kún fún àwọn ohun tí o ṣe.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́