Diutarónómì 32:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Wọ́n ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run+ mú mi bínú;*Wọ́n ti fi àwọn òrìṣà+ wọn tí kò ní láárí múnú bí mi. Torí náà, màá fi àwọn tí kì í ṣe èèyàn+ mú kí wọ́n jowú;Màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀+ mú wọn bínú. Jeremáyà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ǹjẹ́ orílẹ̀-èdè kan ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run rọ́pò ọlọ́run rẹ̀ rí? Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn mi ti fi ohun tí kò wúlò rọ́pò ògo mi.+
21 Wọ́n ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run+ mú mi bínú;*Wọ́n ti fi àwọn òrìṣà+ wọn tí kò ní láárí múnú bí mi. Torí náà, màá fi àwọn tí kì í ṣe èèyàn+ mú kí wọ́n jowú;Màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀+ mú wọn bínú.
11 Ǹjẹ́ orílẹ̀-èdè kan ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run rọ́pò ọlọ́run rẹ̀ rí? Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn mi ti fi ohun tí kò wúlò rọ́pò ògo mi.+