Sáàmù 113:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ta ló dà bíi Jèhófà Ọlọ́run wa,+Ẹni tó ń gbé* ibi gíga? Sáàmù 113:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku. Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+ Lúùkù 1:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Ó ti rẹ àwọn ọkùnrin alágbára sílẹ̀ látorí ìtẹ́,+ ó sì gbé àwọn tó rẹlẹ̀ ga;+
7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku. Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+ Lúùkù 1:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Ó ti rẹ àwọn ọkùnrin alágbára sílẹ̀ látorí ìtẹ́,+ ó sì gbé àwọn tó rẹlẹ̀ ga;+