-
1 Sámúẹ́lì 11:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Nígbà náà, ó ka iye wọn ní Bésékì, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (300,000), àwọn ọkùnrin Júdà sì jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ààbọ̀ (30,000).
-
-
1 Sámúẹ́lì 13:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ìgbà náà ni Sámúẹ́lì dìde, ó sì bá tiẹ̀ lọ láti Gílígálì sí Gíbíà ti Bẹ́ńjámínì, Sọ́ọ̀lù sì ka àwọn èèyàn náà; àwọn tó ṣẹ́ kù sọ́dọ̀ rẹ̀ tó nǹkan bí ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọkùnrin.+
-