1 Sámúẹ́lì 7:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bí Sámúẹ́lì ṣe ń rú ẹbọ sísun lọ́wọ́, àwọn Filísínì gbógun dé láti bá Ísírẹ́lì jà. Jèhófà mú kí ààrá ńlá kan sán+ sórí àwọn Filísínì ní ọjọ́ yẹn, ó kó ìdààmú bá wọn,+ ó sì mú kí Ísírẹ́lì ṣẹ́gun wọn.+ 2 Sámúẹ́lì 22:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í sán ààrá láti ọ̀run;+Ẹni Gíga Jù Lọ mú kí a gbọ́ ohùn rẹ̀.+ Sáàmù 18:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í sán ààrá ní ọ̀run;+Ẹni Gíga Jù Lọ mú kí a gbọ́ ohùn rẹ̀+Pẹ̀lú yìnyín àti ẹyin iná.
10 Bí Sámúẹ́lì ṣe ń rú ẹbọ sísun lọ́wọ́, àwọn Filísínì gbógun dé láti bá Ísírẹ́lì jà. Jèhófà mú kí ààrá ńlá kan sán+ sórí àwọn Filísínì ní ọjọ́ yẹn, ó kó ìdààmú bá wọn,+ ó sì mú kí Ísírẹ́lì ṣẹ́gun wọn.+
13 Nígbà náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í sán ààrá ní ọ̀run;+Ẹni Gíga Jù Lọ mú kí a gbọ́ ohùn rẹ̀+Pẹ̀lú yìnyín àti ẹyin iná.