1 Sámúẹ́lì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà yóò fọ́ àwọn tó ń bá a jà sí wẹ́wẹ́;*+Yóò sán ààrá lù wọ́n láti ọ̀run.+ Jèhófà yóò ṣe ìdájọ́ títí dé gbogbo ìkángun ayé,+Yóò fún ọba rẹ̀ ní agbára+Yóò sì gbé ìwo* ẹni àmì òróró rẹ̀ ga.”+ 1 Sámúẹ́lì 7:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bí Sámúẹ́lì ṣe ń rú ẹbọ sísun lọ́wọ́, àwọn Filísínì gbógun dé láti bá Ísírẹ́lì jà. Jèhófà mú kí ààrá ńlá kan sán+ sórí àwọn Filísínì ní ọjọ́ yẹn, ó kó ìdààmú bá wọn,+ ó sì mú kí Ísírẹ́lì ṣẹ́gun wọn.+
10 Jèhófà yóò fọ́ àwọn tó ń bá a jà sí wẹ́wẹ́;*+Yóò sán ààrá lù wọ́n láti ọ̀run.+ Jèhófà yóò ṣe ìdájọ́ títí dé gbogbo ìkángun ayé,+Yóò fún ọba rẹ̀ ní agbára+Yóò sì gbé ìwo* ẹni àmì òróró rẹ̀ ga.”+
10 Bí Sámúẹ́lì ṣe ń rú ẹbọ sísun lọ́wọ́, àwọn Filísínì gbógun dé láti bá Ísírẹ́lì jà. Jèhófà mú kí ààrá ńlá kan sán+ sórí àwọn Filísínì ní ọjọ́ yẹn, ó kó ìdààmú bá wọn,+ ó sì mú kí Ísírẹ́lì ṣẹ́gun wọn.+