Lúùkù 1:69 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 69 Ó ti gbé ìwo ìgbàlà*+ kan dìde fún wa ní ilé Dáfídì ìránṣẹ́ rẹ̀,+ Ìṣe 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní tòótọ́, Hẹ́rọ́dù àti Pọ́ńtíù Pílátù+ pẹ̀lú àwọn èèyàn àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn èèyàn Ísírẹ́lì kóra jọ ní ìlú yìí láti dojú kọ Jésù, ìránṣẹ́ rẹ mímọ́, ẹni tí o fòróró yàn,+
27 Ní tòótọ́, Hẹ́rọ́dù àti Pọ́ńtíù Pílátù+ pẹ̀lú àwọn èèyàn àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn èèyàn Ísírẹ́lì kóra jọ ní ìlú yìí láti dojú kọ Jésù, ìránṣẹ́ rẹ mímọ́, ẹni tí o fòróró yàn,+