Sáàmù 132:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá mú kí agbára Dáfídì pọ̀ sí i* níbẹ̀. Mo ti ṣètò fìtílà fún ẹni àmì òróró mi.+