1 Kíróníkà 20:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n tún bá àwọn Filísínì jà, Élíhánánì ọmọ Jáírì pa Láámì arákùnrin Gòláyátì+ ará Gátì, ẹni tí igi ọ̀kọ̀ rẹ̀ dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ.*+
5 Wọ́n tún bá àwọn Filísínì jà, Élíhánánì ọmọ Jáírì pa Láámì arákùnrin Gòláyátì+ ará Gátì, ẹni tí igi ọ̀kọ̀ rẹ̀ dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ.*+