1 Sámúẹ́lì 17:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Dáfídì béèrè lọ́wọ́ àwọn ọkùnrin tó dúró nítòsí rẹ̀ pé: “Kí ni wọ́n máa ṣe fún ọkùnrin tó bá mú Filísínì tó wà níbẹ̀ yẹn balẹ̀, tó sì mú ẹ̀gàn kúrò lórí Ísírẹ́lì? Ta tiẹ̀ ni Filísínì aláìdádọ̀dọ́* yìí tí á fi máa pẹ̀gàn ìlà ogun Ọlọ́run alààyè?”+ 2 Àwọn Ọba 19:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ta lo pẹ̀gàn, tí o sì sọ̀rọ̀ òdì sí?+ Ta lo gbé ohùn rẹ sókè sí,+Tí o sì gbé ojú rẹ ga sí? Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì mà ni!+
26 Dáfídì béèrè lọ́wọ́ àwọn ọkùnrin tó dúró nítòsí rẹ̀ pé: “Kí ni wọ́n máa ṣe fún ọkùnrin tó bá mú Filísínì tó wà níbẹ̀ yẹn balẹ̀, tó sì mú ẹ̀gàn kúrò lórí Ísírẹ́lì? Ta tiẹ̀ ni Filísínì aláìdádọ̀dọ́* yìí tí á fi máa pẹ̀gàn ìlà ogun Ọlọ́run alààyè?”+
22 Ta lo pẹ̀gàn, tí o sì sọ̀rọ̀ òdì sí?+ Ta lo gbé ohùn rẹ sókè sí,+Tí o sì gbé ojú rẹ ga sí? Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì mà ni!+