1 Sámúẹ́lì 17:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Filísínì náà wá sọ pé: “Mo pẹ̀gàn ìlà ogun Ísírẹ́lì*+ lónìí yìí. Ẹ rán ọkùnrin kan sí mi, kí a jọ figẹ̀ wọngẹ̀!” Jeremáyà 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣùgbọ́n Jèhófà ni Ọlọ́run lóòótọ́. Òun ni Ọlọ́run alààyè+ àti Ọba ayérayé.+ Nítorí ìbínú rẹ̀, ayé á mì jìgìjìgì,+Kò sì sí orílẹ̀-èdè tó lè fara da ìdálẹ́bi rẹ̀.
10 Filísínì náà wá sọ pé: “Mo pẹ̀gàn ìlà ogun Ísírẹ́lì*+ lónìí yìí. Ẹ rán ọkùnrin kan sí mi, kí a jọ figẹ̀ wọngẹ̀!”
10 Ṣùgbọ́n Jèhófà ni Ọlọ́run lóòótọ́. Òun ni Ọlọ́run alààyè+ àti Ọba ayérayé.+ Nítorí ìbínú rẹ̀, ayé á mì jìgìjìgì,+Kò sì sí orílẹ̀-èdè tó lè fara da ìdálẹ́bi rẹ̀.