1 Sámúẹ́lì 17:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Filísínì náà wá sọ pé: “Mo pẹ̀gàn ìlà ogun Ísírẹ́lì*+ lónìí yìí. Ẹ rán ọkùnrin kan sí mi, kí a jọ figẹ̀ wọngẹ̀!”
10 Filísínì náà wá sọ pé: “Mo pẹ̀gàn ìlà ogun Ísírẹ́lì*+ lónìí yìí. Ẹ rán ọkùnrin kan sí mi, kí a jọ figẹ̀ wọngẹ̀!”