-
1 Sámúẹ́lì 24:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ta tiẹ̀ ni ọba Ísírẹ́lì ń lé kiri? Ta ni ò ń lépa? Ṣé òkú ajá bíi tèmi yìí ni? Àbí ẹyọ eégbọn kan ṣoṣo?+
-
-
2 Àwọn Ọba 8:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Hásáẹ́lì sọ pé: “Báwo ni èmi ìránṣẹ́ rẹ, tí mo jẹ́ ajá lásán-làsàn, ṣe lè ṣe irú nǹkan yìí?” Àmọ́ Èlíṣà sọ pé: “Jèhófà ti fi hàn mí pé wàá di ọba lórí Síríà.”+
-