Òwe 17:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọ̀rẹ́ tòótọ́ máa ń nífẹ̀ẹ́ ẹni nígbà gbogbo,+Ó sì jẹ́ ọmọ ìyá tí a bí fún ìgbà wàhálà.+ Òwe 18:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àwọn ọ̀rẹ́ kan wà tí wọ́n ṣe tán láti ṣe ara wọn níkà,+Àmọ́ ọ̀rẹ́ kan wà tó ń fà mọ́ni ju ọmọ ìyá lọ.+
24 Àwọn ọ̀rẹ́ kan wà tí wọ́n ṣe tán láti ṣe ara wọn níkà,+Àmọ́ ọ̀rẹ́ kan wà tó ń fà mọ́ni ju ọmọ ìyá lọ.+