2 Sámúẹ́lì 21:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nítorí náà, ọba mú àwọn ọmọkùnrin méjèèjì tí Rísípà+ ọmọ Áyà bí fún Sọ́ọ̀lù, ìyẹn, Árímónì àti Méfíbóṣétì, ó tún mú àwọn ọmọkùnrin márààrún tí Míkálì*+ ọmọ Sọ́ọ̀lù bí fún Ádíríélì+ ọmọ Básíláì ará Méhólà.
8 Nítorí náà, ọba mú àwọn ọmọkùnrin méjèèjì tí Rísípà+ ọmọ Áyà bí fún Sọ́ọ̀lù, ìyẹn, Árímónì àti Méfíbóṣétì, ó tún mú àwọn ọmọkùnrin márààrún tí Míkálì*+ ọmọ Sọ́ọ̀lù bí fún Ádíríélì+ ọmọ Básíláì ará Méhólà.