1 Sámúẹ́lì 22:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Áhímélékì bá dá ọba lóhùn pé: “Ta ló ṣeé fọkàn tán* láàárín àwọn ìránṣẹ́ ọba bíi Dáfídì?+ Àna ọba ni,+ ó jẹ́ olórí ẹ̀ṣọ́ rẹ, ẹni iyì sì ni nínú ilé rẹ.+
14 Áhímélékì bá dá ọba lóhùn pé: “Ta ló ṣeé fọkàn tán* láàárín àwọn ìránṣẹ́ ọba bíi Dáfídì?+ Àna ọba ni,+ ó jẹ́ olórí ẹ̀ṣọ́ rẹ, ẹni iyì sì ni nínú ilé rẹ.+