-
1 Sámúẹ́lì 20:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àmọ́ tí bàbá mi bá ń gbèrò láti ṣe ọ́ ní jàǹbá, kí Jèhófà fìyà jẹ èmi Jónátánì gan-an, tí mi ò bá sọ fún ọ, kí n sì jẹ́ kí o lọ ní àlàáfíà. Kí Jèhófà wà pẹ̀lú rẹ,+ bí ó ṣe wà pẹ̀lú bàbá mi tẹ́lẹ̀.+ 14 Àbí, ṣé o ò ní fi ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ hàn sí mi nígbà tí mo ṣì wà láàyè àti nígbà tí mo bá kú?+
-