Sáàmù 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Jèhófà san èrè fún mi nítorí òdodo mi;+Ó san èrè fún mi nítorí pé ọwọ́ mi mọ́.*+ Sáàmù 91:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ọlọ́run sọ pé: “Nítorí ó nífẹ̀ẹ́ mi,* màá gbà á sílẹ̀.+ Màá dáàbò bò ó torí pé ó mọ* orúkọ mi.+