-
1 Sámúẹ́lì 26:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Jèhófà ò ní fẹ́ gbọ́ rárá pé mo gbé ọwọ́ mi sókè sí ẹni àmì òróró Jèhófà!+ Ní báyìí, jọ̀wọ́ jẹ́ ká mú ọ̀kọ̀ àti ìgò omi tó wà níbi orí rẹ̀, kí a sì máa bá tiwa lọ.”
-
-
2 Sámúẹ́lì 1:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ìgbà náà ni Dáfídì sọ fún un pé: “Kí ló dé tí ẹ̀rù ò fi bà ọ́ láti gbé ọwọ́ rẹ sókè láti pa ẹni àmì òróró Jèhófà?”+
-
-
1 Kíróníkà 16:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ó ní, ‘Ẹ má fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi,
Ẹ má sì ṣe ohun búburú sí àwọn wòlíì mi.’+
-