ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 13:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Àmọ́ ní báyìí, ìjọba rẹ kò ní pẹ́.+ Jèhófà máa wá ọkùnrin kan tí ọkàn rẹ̀ fẹ́,+ Jèhófà sì máa yàn án ṣe aṣáájú lórí àwọn èèyàn rẹ̀,+ nítorí pé o ò ṣègbọràn sí ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún ọ.”+

  • 1 Sámúẹ́lì 15:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Sámúẹ́lì wá sọ fún un pé: “Jèhófà ti fa ìṣàkóso Ísírẹ́lì ya kúrò lọ́wọ́ rẹ lónìí, yóò sì fún ọmọnìkejì rẹ tó sàn jù ọ́ lọ.+

  • 1 Sámúẹ́lì 18:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Inú bí Sọ́ọ̀lù gan-an,+ orin yìí sì bà á lọ́kàn jẹ́, ó sọ pé: “Wọ́n fún Dáfídì ní ẹgbẹẹgbàárùn-ún, àmọ́ wọ́n fún mi ní ẹgbẹẹgbẹ̀rún. Ipò ọba nìkan ló kù kí wọ́n fún un!”+

  • 1 Sámúẹ́lì 20:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Ní gbogbo ìgbà tí ọmọ Jésè bá fi wà láàyè lórí ilẹ̀, ìwọ àti ipò ọba rẹ kò ní lè fìdí múlẹ̀.+ Ní báyìí, ní kí wọ́n lọ mú un wá fún mi, nítorí pé ó gbọ́dọ̀ kú.”*+

  • 1 Sámúẹ́lì 23:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ó sọ fún un pé: “Má bẹ̀rù, torí pé Sọ́ọ̀lù bàbá mi kò ní rí ọ mú; ìwọ lo máa di ọba Ísírẹ́lì,+ èmi ni màá di igbá kejì rẹ; Sọ́ọ̀lù bàbá mi náà sì mọ̀ bẹ́ẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́