1 Sámúẹ́lì 25:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, bí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì tí ó dá mi dúró kí n má bàa ṣe ọ́ léṣe+ ti wà láàyè, ká ní o ò tètè wá pàdé mi+ ni, tó bá fi máa di àárọ̀ ọ̀la, kò ní sí ìkankan lára àwọn ọkùnrin* Nábálì tó máa ṣẹ́ kù.”+
34 Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, bí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì tí ó dá mi dúró kí n má bàa ṣe ọ́ léṣe+ ti wà láàyè, ká ní o ò tètè wá pàdé mi+ ni, tó bá fi máa di àárọ̀ ọ̀la, kò ní sí ìkankan lára àwọn ọkùnrin* Nábálì tó máa ṣẹ́ kù.”+