ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 14:50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 50 Orúkọ ìyàwó rẹ̀ ni Áhínóámù ọmọ Áhímáásì. Orúkọ olórí àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ni Ábínérì+ ọmọ Nérì tó jẹ́ arákùnrin bàbá Sọ́ọ̀lù.

  • 1 Sámúẹ́lì 17:55
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 55 Gbàrà tí Sọ́ọ̀lù rí Dáfídì tó ń jáde lọ pàdé Filísínì náà, ó bi Ábínérì+ olórí ọmọ ogun pé: “Ábínérì, ọmọ ta ni ọmọdékùnrin yìí?”+ Ábínérì fèsì pé: “Bí o* ti wà láàyè, ìwọ ọba, mi ò mọ̀!”

  • 2 Sámúẹ́lì 2:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Àmọ́ Ábínérì+ ọmọ Nérì, olórí ọmọ ogun Sọ́ọ̀lù ti mú Íṣí-bóṣétì,+ ọmọ Sọ́ọ̀lù sọdá sí Máhánáímù,+

  • 2 Sámúẹ́lì 3:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Nígbà tí Ábínérì pa dà sí Hébúrónì,+ Jóábù mú un wọnú ibì kan lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹnubodè láti bá a sọ̀rọ̀ ní ìdákọ́ńkọ́. Àmọ́, ibẹ̀ ni ó ti gún un ní ikùn, ó sì kú;+ èyí jẹ́ nítorí pé ó pa* Ásáhélì+ arákùnrin rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́