-
1 Sámúẹ́lì 31:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ìjà náà le mọ́ Sọ́ọ̀lù, ọwọ́ àwọn tafàtafà bà á, wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna.+
-
-
1 Sámúẹ́lì 31:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Bí Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta àti ẹni tó ń bá a gbé ìhámọ́ra pẹ̀lú gbogbo àwọn ọkùnrin rẹ̀ ṣe kú pa pọ̀ ní ọjọ́ yẹn nìyẹn.+
-