1 Sámúẹ́lì 31:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nígbà náà, àwọn Filísínì ń bá Ísírẹ́lì jà.+ Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sá kúrò níwájú àwọn Filísínì, ọ̀pọ̀ lára wọn sì kú sórí Òkè Gíbóà.+ 2 Sámúẹ́lì 1:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹ̀yin òkè Gíbóà,+Kí ìrì má sẹ̀, kí òjò má sì rọ̀ sórí yín,Bẹ́ẹ̀ ni kí pápá má ṣe mú ọrẹ mímọ́+ jáde,Nítorí pé ibẹ̀ ni wọ́n ti sọ apata àwọn alágbára di aláìmọ́,A kò sì fi òróró pa apata Sọ́ọ̀lù mọ́. 2 Sámúẹ́lì 21:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, Dáfídì lọ kó egungun Sọ́ọ̀lù àti egungun Jónátánì ọmọ rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn aṣáájú* Jabeṣi-gílíádì+ tí wọ́n jí egungun náà kó ní ojúde ìlú Bẹti-ṣánì, níbi tí àwọn Filísínì gbé wọn kọ́ sí ní ọjọ́ tí àwọn Filísínì pa Sọ́ọ̀lù ní Gíbóà.+
31 Nígbà náà, àwọn Filísínì ń bá Ísírẹ́lì jà.+ Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sá kúrò níwájú àwọn Filísínì, ọ̀pọ̀ lára wọn sì kú sórí Òkè Gíbóà.+
21 Ẹ̀yin òkè Gíbóà,+Kí ìrì má sẹ̀, kí òjò má sì rọ̀ sórí yín,Bẹ́ẹ̀ ni kí pápá má ṣe mú ọrẹ mímọ́+ jáde,Nítorí pé ibẹ̀ ni wọ́n ti sọ apata àwọn alágbára di aláìmọ́,A kò sì fi òróró pa apata Sọ́ọ̀lù mọ́.
12 Torí náà, Dáfídì lọ kó egungun Sọ́ọ̀lù àti egungun Jónátánì ọmọ rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn aṣáájú* Jabeṣi-gílíádì+ tí wọ́n jí egungun náà kó ní ojúde ìlú Bẹti-ṣánì, níbi tí àwọn Filísínì gbé wọn kọ́ sí ní ọjọ́ tí àwọn Filísínì pa Sọ́ọ̀lù ní Gíbóà.+