-
2 Sámúẹ́lì 2:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ìgbà náà ni àwọn ọkùnrin Júdà wá, ibẹ̀ sì ni wọ́n ti fòróró yan Dáfídì ṣe ọba lórí ilé Júdà.+
Wọ́n sọ fún Dáfídì pé: “Àwọn ará Jabeṣi-gílíádì ló sin Sọ́ọ̀lù.” 5 Torí náà, Dáfídì rán àwọn òjíṣẹ́ sí àwọn ará Jabeṣi-gílíádì, ó sọ fún wọn pé: “Kí Jèhófà bù kún yín, nítorí ẹ fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí Sọ́ọ̀lù, olúwa yín, ní ti pé ẹ sin ín.+
-