-
Ẹ́kísódù 7:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ó sì dájú pé àwọn ará Íjíbítì yóò mọ̀ pé èmi ni Jèhófà+ nígbà tí mo bá na ọwọ́ mi láti bá Íjíbítì jà, tí mo sì mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò láàárín wọn.”
-
-
Sáàmù 78:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Bó ṣe fi àwọn iṣẹ́ àmì rẹ̀ hàn ní Íjíbítì+
Àti àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ ní agbègbè Sóánì,
-
Sáàmù 78:51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Níkẹyìn, ó pa gbogbo àkọ́bí Íjíbítì,+
Ìbẹ̀rẹ̀ agbára ìbímọ wọn nínú àwọn àgọ́ Hámù.
-
-
-