8 Ààlà náà dé Àfonífojì Ọmọ Hínómù,+ ó dé gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àwọn ará Jébúsì+ ní gúúsù, ìyẹn Jerúsálẹ́mù,+ ààlà náà dé orí òkè tó dojú kọ Àfonífojì Hínómù lápá ìwọ̀ oòrùn, èyí tó wà ní ìkángun Àfonífojì* Réfáímù lápá àríwá.
15 Mẹ́ta lára ọgbọ̀n (30) ọkùnrin tó jẹ́ olórí lọ sí ibi àpáta lọ́dọ̀ Dáfídì ní ihò àpáta Ádúlámù,+ lákòókò yìí, àwùjọ àwọn ọmọ ogun Filísínì kan pàgọ́ sí Àfonífojì* Réfáímù.+