1 Àwọn Ọba 1:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Bí Jèhófà ṣe wà pẹ̀lú olúwa mi ọba, bẹ́ẹ̀ ni kí ó wà pẹ̀lú Sólómọ́nì,+ kí ó sì gbé ìtẹ́ rẹ̀ ga ju ìtẹ́ olúwa mi Ọba Dáfídì.”+ 1 Kíróníkà 22:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Òun ló máa kọ́ ilé fún orúkọ mi.+ Á di ọmọ mi, màá sì di bàbá rẹ̀.+ Màá fìdí ìtẹ́ ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ lórí Ísírẹ́lì títí láé.’+ 1 Kíróníkà 28:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Màá fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ títí láé+ tó bá pinnu láti máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́+ mi mọ́, bí ó ti ń ṣe lọ́wọ́lọ́wọ́.’ Sáàmù 89:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 ‘Màá fìdí ọmọ* rẹ+ múlẹ̀ títí láé,Màá gbé ìtẹ́ rẹ ró, á sì wà láti ìran dé ìran.’”+ (Sélà) Sáàmù 89:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àwọn ọmọ* rẹ̀ yóò wà títí láé;+Ìtẹ́ rẹ̀ yóò wà títí lọ bí oòrùn níwájú mi.+
37 Bí Jèhófà ṣe wà pẹ̀lú olúwa mi ọba, bẹ́ẹ̀ ni kí ó wà pẹ̀lú Sólómọ́nì,+ kí ó sì gbé ìtẹ́ rẹ̀ ga ju ìtẹ́ olúwa mi Ọba Dáfídì.”+
10 Òun ló máa kọ́ ilé fún orúkọ mi.+ Á di ọmọ mi, màá sì di bàbá rẹ̀.+ Màá fìdí ìtẹ́ ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ lórí Ísírẹ́lì títí láé.’+
7 Màá fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ títí láé+ tó bá pinnu láti máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́+ mi mọ́, bí ó ti ń ṣe lọ́wọ́lọ́wọ́.’