Diutarónómì 17:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́, kò gbọ́dọ̀ kó ẹṣin rẹpẹtẹ jọ fún ara rẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni kò gbọ́dọ̀ ní kí àwọn èèyàn náà pa dà lọ sí Íjíbítì láti lọ kó ẹṣin sí i wá,+ torí Jèhófà ti sọ fún yín pé, ‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ tún forí lé ọ̀nà yìí mọ́.’ Sáàmù 20:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn kan gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ẹṣin, àwọn míì sì gbẹ́kẹ̀ lé ẹṣin,+Àmọ́, àwa ń ké pe orúkọ Jèhófà Ọlọ́run wa.+ Sáàmù 33:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ìgbẹ́kẹ̀lé nínú ẹṣin pé á gbani là* jẹ́ asán;+Agbára ńlá rẹ̀ kò sọ pé kéèyàn yè bọ́.
16 Àmọ́, kò gbọ́dọ̀ kó ẹṣin rẹpẹtẹ jọ fún ara rẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni kò gbọ́dọ̀ ní kí àwọn èèyàn náà pa dà lọ sí Íjíbítì láti lọ kó ẹṣin sí i wá,+ torí Jèhófà ti sọ fún yín pé, ‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ tún forí lé ọ̀nà yìí mọ́.’
7 Àwọn kan gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ẹṣin, àwọn míì sì gbẹ́kẹ̀ lé ẹṣin,+Àmọ́, àwa ń ké pe orúkọ Jèhófà Ọlọ́run wa.+