ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 9:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Nígbà náà, Dáfídì sọ pé: “Ṣé ẹnì kankan ṣì kù ní ilé Sọ́ọ̀lù tí mo lè fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí nítorí Jónátánì?”+

  • 2 Sámúẹ́lì 16:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ọba wá sọ fún Síbà pé: “Wò ó! Kí gbogbo ohun tó jẹ́ ti Méfíbóṣétì di tìrẹ.”+ Síbà sọ pé: “Mo tẹrí ba níwájú rẹ. Jẹ́ kí n rí ojú rere rẹ, olúwa mi ọba.”+

  • 2 Sámúẹ́lì 19:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Àmọ́ ọba sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi ń sọ̀rọ̀ báyìí? Mo ti pinnu pé kí ìwọ àti Síbà jọ pín oko náà.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́