ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 18:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Gbàrà tí Dáfídì bá Sọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ tán, Jónátánì+ àti Dáfídì wá di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́,* Jónátánì sì bẹ̀rẹ̀ sí í nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara rẹ̀.*+

  • 1 Sámúẹ́lì 18:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Jónátánì àti Dáfídì dá májẹ̀mú,+ torí pé ó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara rẹ̀.*+

  • 1 Sámúẹ́lì 20:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Má ṣe dáwọ́ ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí o ní sí agbo ilé mi dúró,+ kódà nígbà tí Jèhófà bá gbá gbogbo àwọn ọ̀tá Dáfídì kúrò lórí ilẹ̀.”

  • 1 Sámúẹ́lì 20:42
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Jónátánì sọ fún Dáfídì pé: “Máa lọ ní àlàáfíà, nítorí àwa méjèèjì ti fi orúkọ Jèhófà búra+ pé, ‘Kí Jèhófà wà láàárín èmi àti ìwọ àti láàárín àwọn ọmọ* mi àti àwọn ọmọ* rẹ títí láé.’”+

      Dáfídì bá dìde, ó sì lọ, Jónátánì wá pa dà sínú ìlú.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́