2 Sámúẹ́lì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Dáfídì fẹ́ àwọn wáhàrì*+ àti àwọn ìyàwó míì ní Jerúsálẹ́mù lẹ́yìn tí ó dé láti Hébúrónì, wọ́n sì bí ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin púpọ̀ sí i fún Dáfídì.+ 2 Sámúẹ́lì 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, ọba jáde, gbogbo agbo ilé rẹ̀ sì tẹ̀ lé e, àmọ́ ọba ní kí àwọn wáhàrì*+ mẹ́wàá dúró láti máa tọ́jú ilé.
13 Dáfídì fẹ́ àwọn wáhàrì*+ àti àwọn ìyàwó míì ní Jerúsálẹ́mù lẹ́yìn tí ó dé láti Hébúrónì, wọ́n sì bí ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin púpọ̀ sí i fún Dáfídì.+
16 Nítorí náà, ọba jáde, gbogbo agbo ilé rẹ̀ sì tẹ̀ lé e, àmọ́ ọba ní kí àwọn wáhàrì*+ mẹ́wàá dúró láti máa tọ́jú ilé.