-
Jóòbù 30:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Torí mo mọ̀ pé wàá mú kí n kú,
Kí n lọ sí ibi tí gbogbo alààyè á ti pàdé.
-
-
Ìṣe 2:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Nítorí Dáfídì kò lọ sí ọ̀run, àmọ́ òun fúnra rẹ̀ sọ pé, ‘Jèhófà* sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi
-