-
Àwọn Onídàájọ́ 20:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ni àwọn tó ń gbé* Gíbíà bá dìde sí mi, wọ́n sì yí ilé náà ká ní òru. Èmi ni wọ́n fẹ́ pa, àmọ́ dípò ìyẹn, wáhàrì* mi ni wọ́n fipá bá lò pọ̀, ó sì kú.+ 6 Mo wá mú òkú wáhàrì mi, mo gé e sí wẹ́wẹ́, mo sì fi àwọn ègé náà ránṣẹ́ sí gbogbo ilẹ̀ tí Ísírẹ́lì jogún,+ torí ìwà burúkú àti ìwà tó ń dójú tini ni wọ́n hù ní Ísírẹ́lì.
-