ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 7:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ni Jóṣúà bá fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì wólẹ̀ níwájú Àpótí Jèhófà títí di ìrọ̀lẹ́, òun àti àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì, wọ́n sì ń da iyẹ̀pẹ̀ sí orí ara wọn.

  • Ẹ́sítà 4:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nígbà tí Módékáì+ gbọ́ gbogbo ohun tí wọ́n ṣe,+ ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó wọ aṣọ ọ̀fọ̀,* ó sì da eérú sórí. Ó wá lọ sí àárín ìlú, ó gbé ohùn sókè, ó sì ń sunkún kíkankíkan.

  • Jeremáyà 6:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ìwọ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi,

      Wọ aṣọ ọ̀fọ̀,*+ kí o sì yí nínú eérú.

      Ṣọ̀fọ̀ bí ẹni tí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo kú, kí o sì sunkún gidigidi,+

      Torí lójijì ni apanirun máa dé bá wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́