Ìdárò 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó ń sunkún pẹ̀rẹ̀pẹ̀rẹ̀ ní òru,+ omijé sì ń dà ní ojú rẹ̀. Kò sí ìkankan nínú gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ tó máa tù ú nínú.+ Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ti dà á;+ wọ́n ti di ọ̀tá rẹ̀. Ìdárò 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni mo ṣe ń sunkún;+ omijé sì ń dà lójú mi. Nítorí ẹni tó lè tù mí nínú tàbí tó lè tù mí* lára ti jìnnà réré sí mi. Àwọn ọmọ mi kò nírètí, nítorí ọ̀tá ti borí.
2 Ó ń sunkún pẹ̀rẹ̀pẹ̀rẹ̀ ní òru,+ omijé sì ń dà ní ojú rẹ̀. Kò sí ìkankan nínú gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ tó máa tù ú nínú.+ Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ti dà á;+ wọ́n ti di ọ̀tá rẹ̀.
16 Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni mo ṣe ń sunkún;+ omijé sì ń dà lójú mi. Nítorí ẹni tó lè tù mí nínú tàbí tó lè tù mí* lára ti jìnnà réré sí mi. Àwọn ọmọ mi kò nírètí, nítorí ọ̀tá ti borí.