Òwe 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Òmùgọ̀ ọmọ ń fa àjálù bá bàbá rẹ̀,+Oníjà* aya sì dà bí òrùlé tó ń jò ṣáá.+