-
2 Sámúẹ́lì 19:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ìgbà náà ni Ṣíméì+ ọmọ Gérà láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì, tó wá láti Báhúrímù sáré wá, òun àti àwọn ọkùnrin Júdà láti pàdé Ọba Dáfídì,
-