-
1 Àwọn Ọba 2:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 “Ṣíméì ọmọ Gérà ọmọ Bẹ́ńjámínì láti Báhúrímù náà wà nítòsí rẹ. Òun ló ń ṣẹ́ èpè burúkú+ lé mi lórí lọ́jọ́ tí mò ń lọ sí Máhánáímù;+ àmọ́ nígbà tó wá pàdé mi ní Jọ́dánì, mo fi Jèhófà búra fún un pé: ‘Mi ò ní fi idà pa ọ́.’+ 9 Má ṣàìfi ìyà jẹ ẹ́,+ nítorí ọlọ́gbọ́n ni ọ́, o sì mọ ohun tí ó yẹ kí o ṣe sí i; má ṣe jẹ́ kí ó fọwọ́ rọrí kú.”*+
-