1 Kíróníkà 2:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn arábìnrin wọn ni Seruáyà àti Ábígẹ́lì.+ Àwọn ọmọ Seruáyà ni Ábíṣáì,+ Jóábù+ àti Ásáhélì,+ àwọn mẹ́ta. 17 Ábígẹ́lì bí Ámásà,+ bàbá Ámásà sì ni Jétà ọmọ Íṣímáẹ́lì.
16 Àwọn arábìnrin wọn ni Seruáyà àti Ábígẹ́lì.+ Àwọn ọmọ Seruáyà ni Ábíṣáì,+ Jóábù+ àti Ásáhélì,+ àwọn mẹ́ta. 17 Ábígẹ́lì bí Ámásà,+ bàbá Ámásà sì ni Jétà ọmọ Íṣímáẹ́lì.