2 Sámúẹ́lì 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àwọn ọmọ Seruáyà+ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wà níbẹ̀, Jóábù,+ Ábíṣáì+ àti Ásáhélì;+ ẹsẹ̀ Ásáhélì sì yá nílẹ̀ bíi ti àgbọ̀nrín inú pápá. 2 Sámúẹ́lì 3:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Bí Jóábù àti Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ṣe pa Ábínérì+ nítorí pé ó pa Ásáhélì àbúrò wọn ní Gíbíónì lójú ogun+ nìyẹn. 2 Sámúẹ́lì 23:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ásáhélì+ arákùnrin Jóábù wà lára àwọn ọgbọ̀n (30) náà, àwọn ni: Élíhánánì ọmọ Dódò ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,+
18 Àwọn ọmọ Seruáyà+ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wà níbẹ̀, Jóábù,+ Ábíṣáì+ àti Ásáhélì;+ ẹsẹ̀ Ásáhélì sì yá nílẹ̀ bíi ti àgbọ̀nrín inú pápá.
30 Bí Jóábù àti Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ṣe pa Ábínérì+ nítorí pé ó pa Ásáhélì àbúrò wọn ní Gíbíónì lójú ogun+ nìyẹn.
24 Ásáhélì+ arákùnrin Jóábù wà lára àwọn ọgbọ̀n (30) náà, àwọn ni: Élíhánánì ọmọ Dódò ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù,+