2 Sámúẹ́lì 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ábúsálómù ọmọ Dáfídì ní àbúrò obìnrin kan tó rẹwà, Támárì+ ni orúkọ rẹ̀, ìfẹ́ rẹ̀ sì ti kó sí Ámínónì+ ọmọ Dáfídì lórí.
13 Ábúsálómù ọmọ Dáfídì ní àbúrò obìnrin kan tó rẹwà, Támárì+ ni orúkọ rẹ̀, ìfẹ́ rẹ̀ sì ti kó sí Ámínónì+ ọmọ Dáfídì lórí.