ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 17:50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 50 Bí Dáfídì ṣe fi kànnàkànnà àti òkúta kan ṣẹ́gun Filísínì náà nìyẹn; ó mú Filísínì náà balẹ̀, ó sì pa á, bó tilẹ̀ jẹ́ pe kò sí idà lọ́wọ́ Dáfídì.+

  • 1 Sámúẹ́lì 18:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Àwọn obìnrin tó ń ṣe ayẹyẹ náà ń kọrin pé:

      “Sọ́ọ̀lù ti pa ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọ̀tá,

      Àmọ́ Dáfídì pa ẹgbẹẹgbàárùn-ún ọ̀tá.”+

  • 1 Sámúẹ́lì 19:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ó fi ẹ̀mí rẹ̀ wewu* kó lè pa Filísínì náà,+ tí Jèhófà sì mú kí gbogbo Ísírẹ́lì ṣẹ́gun* lọ́nà tó kàmàmà. O rí i, inú rẹ sì dùn gan-an. Kí ló wá dé tí o fẹ́ fi pa Dáfídì láìnídìí, tí wàá sì ní ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ lọ́rùn?”+

  • 2 Sámúẹ́lì 5:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Torí náà, Dáfídì ṣe ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún un gẹ́lẹ́, ó sì pa àwọn Filísínì+ láti Gébà+ títí dé Gésérì.+

  • 2 Sámúẹ́lì 8:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nígbà tí àwọn ará Síríà tó wà ní Damásíkù+ wá ran Hadadésà ọba Sóbà lọ́wọ́, Dáfídì pa ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) lára àwọn ará Síríà+ náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́