-
Jóṣúà 17:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù sọ fún Jóṣúà pé: “Kí ló dé tí o fi kèké yan ilẹ̀ kan,+ tí o sì fún wa* ní ìpín kan ṣoṣo pé kó jẹ́ ogún wa? Èèyàn púpọ̀ ni wá, torí Jèhófà ti bù kún wa títí di báyìí.”+ 15 Jóṣúà fún wọn lésì pé: “Tó bá jẹ́ pé ẹ pọ̀ tó bẹ́ẹ̀, ẹ lọ sínú igbó, kí ẹ sì ṣán ibì kan fún ara yín níbẹ̀, ní ilẹ̀ àwọn Pérísì+ àti àwọn Réfáímù,+ tó bá jẹ́ pé agbègbè olókè Éfúrémù+ ti kéré jù fún yín.”
-