1 Sámúẹ́lì 17:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Filísínì náà wá sọ pé: “Mo pẹ̀gàn ìlà ogun Ísírẹ́lì*+ lónìí yìí. Ẹ rán ọkùnrin kan sí mi, kí a jọ figẹ̀ wọngẹ̀!” 1 Sámúẹ́lì 17:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Dáfídì fún Filísínì náà lésì pé: “Ìwọ ń mú idà àti ọ̀kọ̀ àti ẹ̀ṣín*+ bọ̀ wá bá mi jà, ṣùgbọ́n èmi ń bọ̀ wá bá ọ ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ Ọlọ́run ìlà ogun Ísírẹ́lì, ẹni tí o pẹ̀gàn.*+ 2 Àwọn Ọba 19:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ta lo pẹ̀gàn, tí o sì sọ̀rọ̀ òdì sí?+ Ta lo gbé ohùn rẹ sókè sí,+Tí o sì gbé ojú rẹ ga sí? Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì mà ni!+
10 Filísínì náà wá sọ pé: “Mo pẹ̀gàn ìlà ogun Ísírẹ́lì*+ lónìí yìí. Ẹ rán ọkùnrin kan sí mi, kí a jọ figẹ̀ wọngẹ̀!”
45 Dáfídì fún Filísínì náà lésì pé: “Ìwọ ń mú idà àti ọ̀kọ̀ àti ẹ̀ṣín*+ bọ̀ wá bá mi jà, ṣùgbọ́n èmi ń bọ̀ wá bá ọ ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ Ọlọ́run ìlà ogun Ísírẹ́lì, ẹni tí o pẹ̀gàn.*+
22 Ta lo pẹ̀gàn, tí o sì sọ̀rọ̀ òdì sí?+ Ta lo gbé ohùn rẹ sókè sí,+Tí o sì gbé ojú rẹ ga sí? Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì mà ni!+