-
Sáàmù 18:25-30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ìwọ jẹ́ adúróṣinṣin sí ẹni tó jẹ́ adúróṣinṣin;+
Ìwọ ń hùwà àìlẹ́bi sí ọkùnrin aláìlẹ́bi;+
26 Ìwọ jẹ́ mímọ́ sí ẹni tí ó mọ́,+
Àmọ́ ìwọ ń jẹ́ kí àwọn oníbékebèke mọ̀ pé òmùgọ̀ ni wọ́n.+
28 Jèhófà, ìwọ lò ń tan fìtílà mi,
Ọlọ́run mi tó ń tan ìmọ́lẹ̀ sí òkùnkùn+ mi.
Apata ló jẹ́ fún gbogbo àwọn tó fi í ṣe ibi ààbò.+
-