ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 22:26-31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ìwọ jẹ́ adúróṣinṣin sí ẹni tó jẹ́ adúróṣinṣin;+

      Ìwọ ń hùwà àìlẹ́bi sí akíkanjú ọkùnrin aláìlẹ́bi;+

      27 Ìwọ jẹ́ mímọ́ sí ẹni tí ó mọ́,+

      Àmọ́ ìwọ ń jẹ́ kí àwọn oníbékebèke mọ̀ pé òmùgọ̀ ni wọ́n.*+

      28 Ò ń gba àwọn ẹni rírẹlẹ̀ là,+

      Ṣùgbọ́n o kì í fi ojú rere wo àwọn agbéraga, o sì ń rẹ̀ wọ́n wálẹ̀.+

      29 Jèhófà, ìwọ ni fìtílà mi,+

      Jèhófà ló sì ń tan ìmọ́lẹ̀ sí òkùnkùn mi.+

      30 Ìrànlọ́wọ́ rẹ ni mo fi lè gbéjà ko àwọn jàǹdùkú;*

      Agbára Ọlọ́run ni mo fi lè gun ògiri.+

      31 Pípé ni ọ̀nà Ọlọ́run tòótọ́;+

      Ọ̀rọ̀ Jèhófà jẹ́ èyí tí a yọ́ mọ́.+

      Apata ló jẹ́ fún gbogbo àwọn tó fi í ṣe ibi ààbò.+

  • Jóòbù 34:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Torí ó máa fi ohun tí èèyàn bá ṣe san án lẹ́san,+

      Ó sì máa mú kó jèrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.

  • Jeremáyà 32:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ìpinnu rẹ* ga, àwọn iṣẹ́ rẹ sì tóbi,+ ìwọ tí ojú rẹ ń wo gbogbo ọ̀nà àwọn èèyàn,+ láti san èrè fún ẹnì kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀ àti gẹ́gẹ́ bí ohun tí ó ṣe.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́