Jẹ́nẹ́sísì 49:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ní ti ìwọ Júdà,+ àwọn arákùnrin rẹ yóò yìn ọ́.+ Ọwọ́ rẹ yóò wà ní ọrùn àwọn ọ̀tá rẹ.+ Àwọn ọmọ bàbá rẹ yóò tẹrí ba fún ọ.+
8 “Ní ti ìwọ Júdà,+ àwọn arákùnrin rẹ yóò yìn ọ́.+ Ọwọ́ rẹ yóò wà ní ọrùn àwọn ọ̀tá rẹ.+ Àwọn ọmọ bàbá rẹ yóò tẹrí ba fún ọ.+