-
Jẹ́nẹ́sísì 49:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
49 Jékọ́bù sì pe àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, ó sọ pé: “Ẹ kó ara yín jọ, kí n lè sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí yín lọ́jọ́ iwájú.
-
-
Diutarónómì 33:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Bí Mósè èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ ṣe súre fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kó tó kú nìyí.+
-